FIRST TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA SS2

Senior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com

NERDC Curriculum Yoruba SS2

SS2 First Term Yoruba Scheme of work Lagos State

OSE1

EDE – Atunyewo lori Aroko ajemo isipaya:

 • Ilana ero aroko ajemo isipaya
 • Akole, Ifaara, koko oro, agbalo gbdo
 • Alaye kikun lori eto ipin afo
 • Kiko aroko lori akole bii Omi, Iyan,Oja ati bee lo

ASA – Atunyewo lori eko ile: Ibowofagba, ikini, bi o se ye ni gbogbo igba, suuru, otito sise, iforiti, igboran ati bee bee lo

LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan ti rgbe Akomolede fi owo si.

OSE2

EDE – Atunyewo lori silebu ede Yoruba:

 • Oriki silebuSilebu oni faweli kan (F)
 • Silebu alakanpo konsonanti ati faweli
 • Pipin oro si silebu

ASA – Atunyewo ise abinibi:

 • Ise agbe, gege bi ise abinibi gbogbo wa. Awon ohun elo ise agbe: Oko, Ada, ati bee bee lo
 • Ise agbede, ise alapata, ise akope ati ise gbenagbena ati bee bee lo

LITIRESO – Itesiwaju lori atupale awon iwe Litireso:

 • Awon eda itan
 • Ibudo itan

OSE 3

EDE – Atunyewo aroko onisorongbesi:

 • Alaye lori oro onisorongbesi
 • Kiko aroko onisorongbesi to dale isele awujo

ASA – Ona ibanisoro:

 • Lilo awon eya ara fun ibanisoro bii sise ni ni eekanna, ori gbongbon, oju sise, ara mimi, titenimole, imu yinyin ati iparoko.

LITIRESO – Itupale iwe litireso: Ahunpo itan ati awon asa Yoruba to seyo ninu itan naa

OSE 4

EDE – Atunyewo ihun oro

 1. Siseda oro rouko
 2. Alaye lori awon oro oruko ti a ko seda sugbon ti won dabi eyi ti aseda bi ile, oba, omo, iay ati bee bee lo

ASA – Itesiwaju eko lori ona ibanisoro:

 1. Ibanisoro ni aye ode oni bi iwe iroyin, telifonu, redio, foonu, foonu alagbekaa 1 meeli ati fasi (fax)

LITIRESO – Sise atupale asayan iwe litireso:

 1. Awon ilo ede/Akanlo ede
 2. Sise orinkinniwin won

OSE 5

EDE – Onka Yoruba:

 1. Lati egbaa de oke meedogbon on (2,000 – 500,000)

ASA – Awon orisa ile Yoruba:

 1. Ogun, Obatala, Esu
 2. Awon ohun ti a fi n bo eon ati oriki okookan won

LITIRESO – Kika iwe asayan ti ijoba yan

OSE 6

EDE – Onka Yoruba:

 1. Lati oke meedogbon on de Aadota (500,000 – 1,000,000)

ASA – Awon orisa ile Yoruba ati bi a se n bo won:

 1. Orunmila, Sango
 2. Awon ohun ti a fi n bo won ati oriki okookan won

LITIRESO – Kika sayan iwe litereso Yoruba ti ajo WAEC/NECO yan

OSE 7

EDE – Atunyewo awon eya ara ifo:

 1. Lilo awon eya ara ifo
 2. Alaye lori afipe asunsi ati afipe akanmole

ASA – Awon orisa ati bi a se n bo won:

 1. Awon orisa miiran ni agbegbe awon akeeko
 2. Ipo orisa ni ile Yourba
 3. Pataki orisa lawujo Yoruba

LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan

OSE 8

EDE – Atunyewo awon iro ninu ede Yoruba:

 1. Iro faweli, iro konsonanti ati iro ohun

ASA – Ero ati igbagbo awon Yoruba lori Oso ati Aje:

 1. Ise ti awon aje n se ninu isegun ati iwosan

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

OSE 9

EDE – Atunyewo apejuwe iro konsonanti ati iro faweli:

 1. Yiya ate faweli ati konsonanti
 2. Sise apejuwe awon iro konsonanti ati faweli leyo kookan

ASA – Ero ati igbagbo Yoruba lori akudaaya ati abami eda:

 1. Akudaaya ati abami eda bii Egbere, Iwin, Alujonu, Ebora ati bee bee lo

LITIRESO – Kikai we litireso ti ijoba yan

OSE 10

EDE – Atunyewo eko lori ami ohun:

 1. Kiko ami ohun Yoruba meteeta
 2. Alaye lori ise ti ami ohun n se ninu ede Yoruba

ASA – Igbagbo Yoruba nipa ori tabi eleeda:

LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan fun saa yi

OSE 11 & 12

Atunyewo lori gbogbo ise saa yii ati idanwo ipari saa keta lori Ede, Asa ati Litireso ede Yoruba

OSE1

OSE1

OSE1

OSE1

Lessonplan

Get Lesson plans, Lesson notes, Scheme of work, Exam Questions, Test Questions for all subject for Primary school and Secondary School.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button
Share via
Share
Close
Close

Adblock Detected

Please, Disable Adblock to access this website.
error: Please, enable javascript
Thanks for the kind gesture
Please Like and follow us