FIRST TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA JSS 3 (Basic 9)

Junior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com

NERDC Curriculum Yoruba JSS3

JSS3 First Term Yoruba Scheme of work Lagos State

Week 1

EDE – Atunyewo fonoloji Ede Yoruba iparoje ati isunki

ASA – Isinku ni ile Yoruba

LITIRESO – Awon Ewi Alohun ti o je mo esin abalaye iyere: ifa, Sango pipe

Week 2

EDE – Aroko Alalaye

ASA – Ogun pinpin

LITIRESO – Awon ewi alohun ti o je mo esin abalaye – yala, iwi egungun, oya pipe

Week 3

EDE – Atunyewo awon apola ninu gbolohun ede Yoruba. Apola oruko ati Apola ise

ASA – Asa ati suyo ninu awon ewi atohun ti o fem o esin abalaye ijale, iwi egungun, Oya pipe, Sango pipe.

LITIRESO – Kika iwe litireso apileke ti Yoruba

Week 4

EDE – Atunyewo awon eye gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba

ASA – Atunyewo awon ere idaraye ile Yoruba

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

Week 5

EDE – Gbolohun ibeere – awon iwure ti a fi n se ibeere da, nko, nje, taki

ASA – Atunyewo asa iran a enilowo, owe, aaro, obese, esuse, ajo

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

Week 6

EDE – Atunyewo ami ohun ati silebu

ASA – Atunyewo asa iran ra eni lowo owe, aaro, obese, esusu, ajo

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

Week 7

EDE – Atunyewo lori ibasepo laarin awe gbolohun ede Yoruba

ASA – Awon orisa ile Yoruba obalale

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

Week 8

EDE – Atunyewo orisirisii eya awe gbolohun

ASA – Awon oris ile Yoruba – Ogun

LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan

Week 9 – Akaye: Kika Akaye lori itan aroso

Week 10 – Apeko: Awon gbolohun keekee Yoruba

Week 11 & 12 – Atunyewo ise saa yii

Week 13 – Idanwo ase kagba fun saa yii

One Comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button