FIRST TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA SS1
Senior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com
NERDC Curriculum Yoruba SS1
SS1 First Term Yoruba Scheme of work Lagos State
Week 1 – Atunyewo awon eya ara ifo
- Atunyewo Eko ile- asa ikini
- Atunyewo orisirisi eya litireso
Week 2 – Itesiwaju lori eko nipa iro ede
Ise abinibi
Eko lori igbadun ti o wa ninu litireso alohun
Week 3 – Itesiwaju lori eko nipa iro ede
Owe
Eko lori igbadun ti o wa ninu litireso alohun
Week 4 – Itesiwaju lori eko nipa iro ede
Sise ounje awujo Yoruba
Ogbon itopinpin litireso ede Yoruba
Week 5 – Itesiwaju lori eko lori iro ede (iro ohun )
Awon owe ti o je mo asa yoruba
Itupale asayan iwe itan aroso ti ajo WAEC/NECO yan
Week 6 – Silebu
Awon owe ti o suyo ninu ise ati ise Yoruba
Week 7 – Akoto ede Yoruba
Iwa omoluabi ati anfaani re
Week 8 – Aroko kiko
Ise abinibi ile Yoruba
Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan.