FIRST TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA JSS 1 (Basic 7)
Junior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com
NERDC Curriculum Yoruba JSS1
JSS1 First Term Yoruba Scheme of work Lagos State
SAA ETO ISE FUN SAA KIN-IN-NI
Week 1 – Alifabeeti ede Yoruba
- Itan isedale Yoruba
- Oriki litireso
Week 2 – Ami ohun lori awon faweeli ati oro onisilebu kan
- Ile-ife saaju dide oduduwa
Week 3 – Ami ohun
- Awon eya Yoruba ati ibi ti won tedo si
- Awon ohun to ya litireso soto si ede ojoojumo
Week 4 – Silebu
- Ikini ni aarin eya Yoruba, ounje won ati bi won se n se won
Week 5 – Akoto ode oni
- Ikini II Akoko
- Litireso alohun to je mo Aseye
Week 6 – Akoto awon oro ti a sunki
- Iwulo Ede Yoruba
- Litireso Alohun to je mo esin
Week 7 – Onka Yoruba lati ookan de aadota (1-50)
- Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba
- Litireso Apileko
Week 8 – Onka lati ookan lelaadota de ogorun-un (51-100)
- Asa ati ohun-elo isomoloruko
Week 9 – Oriki ati liana kiko aroko Yoruba pelu apeere
- Isomoloruko II
- Awon litir//so Apileko – Ere onitan.
Week 10 – Aroko atonisona Alapejuwe
- Oye jije ati ohu elo oye jije
- Awon litireso apileko ewi
Week 11 – Isori oro +ninu gbolohun
- Isinku nile Yoruba