FIRST TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA SS3
Senior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com
NERDC Curriculum Yoruba SS3
SS3 First Term Yoruba Scheme of work Lagos State
FIRST TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS3 YORUBA LANGUAGE
OSE 1
EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun
ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. Ayipada to ti de ba Asa isinku abinibi tabi atohunrinwa
LITIRESO – Agbeyewo iwe ti Ajo WAEC/NECO yan. Onkowe, itan ni soki ati awon amuye miiran
OSE 2
EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Gbolohun eleyo oro ise, gbolohun olopo oro-ise, sise akojopo gbolohun eleyo oro-ise.
ASA – Eto ogunjije. Awon iran/orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 3
EDE – Itesiwaju lori ihun oro
Dida oro oruko ti asede mo yato si eyi ti a ko seda
Itupale oro oruko eniyan, sise akojopo oro oruko
ASA – Itesiwaju eko lori Egbe Awo
Orisirisii egbe Awo ti o wa nile Yoruba
Alaye kiku lori ipa ti awon egbe wonyii n ko ninu eto oselu
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 4
EDE – Iba Isele (Aseranwo oro-ise)
- Orisii iba isele to wa Asetan, Aterere, Aisetan abbl
- Awon wunreni ti o toka iba isele ninu gbolohun
ASA – Itesiwaju eko nipa igbagbo ati ero Yoruba nipa oso ati aje. Ero ati igbagbo awon eya miiran ni orile ede Naijiiria ati orile ede miiran nipa oso ati aje
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 5
EDE – Itesiwaju lori Oro Agbaso
Yiyo oro enu oloro si oro agbaso, fifi eti si sise, kika ati jijabo iroyin ipade
Yiya afo agba oro si afo-asafo
ASA – Itesiwaju lori Eko ile ati imototo itoju ara, bi a se nkini, oro siso, onje jije ati awo fifo
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 6
EDE – Itesiwaju lori oro aroko oniroyin, ijiroro kikun lori awon ori oro to je mo aroko oniroyin. Kiko ilapa ero
ASA – Itesiwaju eko lori ojuse eni ni awujo pataki ojuse eni ninu ile, laarin ebi, egbe, adugbo, abbl
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 7
EDE – Iyato to wa laarin Oro Aponle ati Apola Aponle, alaye kikun. Oro Aponle ati Apola Aponle, titoka si ilo oro aponle ninu gbolohun, fifa oro aponle ati apola aponle yo ninu gbolohun tabi ipinro, sise alaye ise okookan won ninu gbolohun. Alopo mejeeji ninu gbolohun
ASA – Itesiwaju lori oran dida ati ijiya ti o to ipa ti awon agbefoba ati agbonfinro n ko ninu sise eto idajo fun arufin ati odaran, orisii eto idajo ati oan ti a o gba fi iya je odaran laye atijo ati ode oni
LITIRESO – Ayewo finifini lori awon Asayn itandowe. Itandowe siso, itandowe kookan ni oloro geere titoba si oew ati asa to suyo ninu itan kookan, isowolo ede ninu itan to di owe kookan.
OSE 8
EDE – itesiwaju ninu aayan ogbufo. Ogbon ti a n ta fun aayan ogbufo lati ede geesi si ojulowo ede Yoruba. Fifoye itumo ayoka oloro geere to ta koko jut i ateyinwa lo lati inu ede geesi si ojulowo Yoruba ajumolo
ASA – Itesiwaju nipa igbagbo awon Yoruba si aseyin waye ati abami eda
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 9
EDE – Itesiwaju Akaye Ayoka (orisirisi, agbeyewo orisirisi, akaye bii oloro geere, ewi, ere onitan, ati orisii ayoka danra wo
ASA – Itesiwaju lori eewo. Awon eewo ti aisan mu wa akojopo aisan ati eewo ti alaisan kookan ko gbodo deja, anfaani awon eewo fun awon alaisan
LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 10
EDE – Atunyewo awon isori oro-oruko, oro aropo oruko, oro ise, sise itupale gbolohun kekere si isori oro
ASA – Itesiwaju lori oruko ile Yoruba, oruko Amutorunwa, oruko abiso ati oriki inagije LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan
OSE 11
Atunyewo eko lori ise saa yii ninu ede, asa ati litireso
OSE 12
Akanse idanwo lori eko, ede, asa ati litireso