SECOND TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA SS3

Senior Secondary School Curriculum Yoruba – Edudelight.com

NERDC Curriculum Yoruba SS3

SS3 Second Term Yoruba Curriculum Lagos State

SECOND TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS3 YORUBA LANGUAGE

OSE 1

EDE – Atunyewo eko kikun lori silebu ede Yoruba

ASA – Atunyewo eko lori Elegbejegbe, iro-si-iro

LITIRESO – Agbeyweo asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan Onkowe, eda itan ati awon amuye inu itan yii

OSE 2

EDE – Atunyewo eko lori eko fonoloji ede Yoruba

B.A foniimu konsonanti, faweli, ohun, konsonanti aranmupe, asesilebu

Eda foniimu, konsonanti ati faweli

ASA – Agbeyewo awon orisa ile Yoruba Obatala, Orunmila/Ifa. Itan ni soki nipa awon Aworo Orisa

LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan

OSE 3

EDE – Atunyewo eko lori oro ayalo minu oro ayalo wo inu ede Yoruba

ASA – Atunyewo eko lori eko ebi ati iserun eni

LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan

OSE 4

EDE – Atunyewo kikun lori eko ihun oro ai iseda oro-oruko

ASA – Atunyewo kikun lori ede eto iselu abinibi ati ode-oni

LITIRESO – Itupale asayan iwe ajo WAEC/NECO yan

OSE 5

EDE – Atunyewo eko lori isori oro; oro oruko, oro aropo oruko, aoro aropo afarajoruko, oro ise

ASA – Atunyewo eko lori oge sise, aso wiwo, itoju ara, ila kiko abbl.

LITIRESO – Atunyewo eko lori alo apamo, apagbe ati itandowe abbl

OSE 6

EDE – Atunyewo eko lori isori ori apejuwe, oro aponle, oro asopo ati oro atokun

ASA – Atunyewo kikun lori asa igbeyawo ni ile Yoruba

LITIRESO – Itupale Asayan iwe ti ajo WAEC/NECo yan

Lessonplan

Get Lesson plans, Lesson notes, Scheme of work, Exam Questions, Test Questions for all subject for Primary school and Secondary School.

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Back to top button
Share via
Share
Close
Close

Adblock Detected

Please, Disable Adblock to access this website.
error: Please, enable javascript
Thanks for the kind gesture
Please Like and follow us