THIRD TERM SCHEME OF WORK FOR YORUBA SS2
Senior Secondary School Scheme of work Yoruba – Edudelight.com
NERDC Curriculum Yoruba SS2
SS2 Third Term Yoruba Scheme of work Lagos State
SECOND TERM ILAANA ISE NI SAA KETA FUN SS2
OSE 1
EDE – Atunyewo lori Aroko ajemo isipaya:
- Ilana ero aroko ajemo isipaya
- Akole, Ifaara, koko oro, agbalo gbdo
- Alaye kikun lori eto ipin afo
- Kiko aroko lori akole bii Omi, Iyan,Oja ati bee lo
ASA – Atunyewo lori eko ile:
- Ibowofagba, ikini, bi o se ye ni gbogbo igba, suuru, otito sise, iforiti, igboran ati bee bee lo
LITIRESO – Itupale asayan iwe ti ajo WAEC/NECO yan ti rgbe Akomolede fi owo si.
OSE 2
EDE – Atunyewo lori silebu ede Yoruba:
- Oriki silebu
- Silebu oni faweli kan (F)
- Silebu alakanpo konsonanti ati faweli
- Pipin oro si silebu
ASA – Atunyewo ise abinibi:
- Ise agbe, gege bi ise abinibi gbogbo wa. Awon ohun elo ise agbe: Oko, Ada, ati bee bee lo
- Ise agbede, ise alapata, ise akope ati ise gbenagbena ati bee bee lo
LITIRESO – Itesiwaju lori atupale awon iwe Litireso:
- Awon eda itan
- Ibudo itan
OSE 3
EDE – Atunyewo aroko onisorongbesi:
- Alaye lori oro onisorongbesi
- Kiko aroko onisorongbesi to dale isele awujo
ASA – Ona ibanisoro:
- Lilo awon eya ara fun ibanisoro bii sise ni ni eekanna, ori gbongbon, oju sise, ara mimi, titenimole, imu yinyin ati iparoko.
LITIRESO – Itupale iwe litireso: Ahunpo itan ati awon asa Yoruba to seyo ninu itan naa
OSE 4
EDE – Atunyewo ihun oro
- Siseda oro rouko
- Alaye lori awon oro oruko ti a ko seda sugbon ti won dabi eyi ti aseda bi ile, oba, omo, iay ati bee bee lo
ASA – Itesiwaju eko lori ona ibanisoro:
- Ibanisoro ni aye ode oni bi iwe iroyin, telifonu, redio, foonu, foonu alagbekaa 1 meeli ati fasi (fax)
LITIRESO – Sise atupale asayan iwe litireso:
- Awon ilo ede/Akanlo ede
- Sise orinkinniwin won
OSE 5
EDE – Onka Yoruba:
- Lati egbaa de oke meedogbon on (2,000 – 500,000)
ASA – Awon orisa ile Yoruba:
- Ogun, Obatala, Esu
- Awon ohun ti a fi n bo eon ati oriki okookan won
LITIRESO – Kika iwe asayan ti ijoba yan
OSE 6
EDE – Onka Yoruba:
- Lati oke meedogbon on de Aadota (500,000 – 1,000,000)
ASA – Awon orisa ile Yoruba ati bi a se n bo won:
- Orunmila, Sango
- Awon ohun ti a fi n bo won ati oriki okookan won
LITIRESO – Kika sayan iwe litereso Yoruba ti ajo WAEC/NECO yan
OSE 7
EDE – Atunyewo awon eya ara ifo:
- Lilo awon eya ara ifo
- Alaye lori afipe asunsi ati afipe akanmole
ASA – Awon orisa ati bi a se n bo won:
- Awon orisa miiran ni agbegbe awon akeeko
- Ipo orisa ni ile Yourba
- Pataki orisa lawujo Yoruba
LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan
OSE 8
EDE – Atunyewo awon iro ninu ede Yoruba:
- Iro faweli, iro konsonanti ati iro ohun
ASA – Ero ati igbagbo awon Yoruba lori Oso ati Aje:
- Ise ti awon aje n se ninu isegun ati iwosan
LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan
OSE 9
EDE – Atunyewo apejuwe iro konsonanti ati iro faweli:
- Yiya ate faweli ati konsonanti
- Sise apejuwe awon iro konsonanti ati faweli leyo kookan
ASA – Ero ati igbagbo Yoruba lori akudaaya ati abami eda:
- Akudaaya ati abami eda bii Egbere, Iwin, Alujonu, Ebora ati bee bee lo
LITIRESO – Kikai we litireso ti ijoba yan
OSE 10
EDE – Atunyewo eko lori ami ohun:
- Kiko ami ohun Yoruba meteeta
- Alaye lori ise ti ami ohun n se ninu ede Yoruba
ASA – Igbagbo Yoruba nipa ori tabi eleeda:
LITIRESO – Kika iwe litireso Yoruba ti ijoba yan fun saa yi
OSE 11 & 12
Atunyewo lori gbogbo ise saa yii ati idanwo ipari saa keta lori Ede, Asa ati Litireso ede Yoruba